Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 11:39 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lẹ́yìn oṣù méjì náà, ó padà tọ baba rẹ̀ wá òun sì ṣe sí i bí ẹ̀jẹ́ tí ó ti jẹ́. Ọmọ náà sì jẹ́ wúndíá tí kò mọ ọkùnrin rí.Èyí sì bẹ̀rẹ̀ àṣà kan ní Ísírẹ́lì

Ka pipe ipin Onídájọ́ 11

Wo Onídájọ́ 11:39 ni o tọ