Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 11:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jẹ́fítà ará Gílíádì jẹ́ akọni jagunjagun. Gílíádì ni baba rẹ̀; ṣùgbọ́n ìyá rẹ̀ jẹ́ aṣẹ́wó.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 11

Wo Onídájọ́ 11:1 ni o tọ