Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 1:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ayọ́lẹ̀wò náà rí ọkùnrin kan tí ń jáde láti inú ìlú náà wá, wọ́n sì wí fún un pé, “Fi ọ̀nà àti wọ ìlú yìí hàn wá, àwa ó sì dá ẹ̀mìí rẹ sí, a ó sì ṣe àánú fún ọ.”

Ka pipe ipin Onídájọ́ 1

Wo Onídájọ́ 1:24 ni o tọ