Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ọbadáyà 1:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ilé Jákọ́bù yóò sì jẹ́ ináàti ilé Jósẹ́fù ọwọ́ ináilé Ísọ̀ yóò jẹ àkékù koríkowọn yóò fi iná sí i,wọn yóò jo run.Kì yóò sí ẹni tí yóò kù ní ilé Ísọ̀.”Nítorí Olúwa ti wí i.

Ka pipe ipin Ọbadáyà 1

Wo Ọbadáyà 1:18 ni o tọ