Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ọbadáyà 1:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìran ti Ọbadáyà. Èyí ni Olúwa Ọlọ́run wí nípa Édómù.Àwa ti gbọ́ ohùn kan láti ọ̀dọ̀ Olúwa wá:A sì ti rán ikọ̀ kan sí gbogbo aláìkọlà láti sọ pé,“Ẹ dìde, ẹ jẹ́ kí a dìde ogun sí i.”

Ka pipe ipin Ọbadáyà 1

Wo Ọbadáyà 1:1 ni o tọ