Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 9:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọn yóò ṣe ti wọn ní ìdajì ọjọ́ kẹ́rìnlá oṣù kejì. Wọn yóò jẹ ẹran náà, pẹ̀lú àkàrà aláìwú àti ewúro.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 9

Wo Nọ́ḿbà 9:11 ni o tọ