Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 7:88 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àpapọ̀ iye ẹran fún ọrẹ àlàáfíà jẹ́ màlúù mẹ́rìnlélógún (24), ọgọ́ta (60) àgbò, ọgọ́ta (60) akọ ewúrẹ́ àti ọgọ́ta (60) akọ ọ̀dọ́ màlúù ọlọ́dún kan. Wọ̀nyí ni ọrẹ ìyàsímímọ́ pẹpẹ lẹ́yìn tí a ta òróró sí i.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 7

Wo Nọ́ḿbà 7:88 ni o tọ