Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 7:37 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọrẹ tí ó kó wá ni àwo fàdákà kan tí ìwọ̀n rẹ̀ jẹ́ àádóje (130) ṣékélì àti àwokòtò tí ìwọ̀n rẹ̀ jẹ́ àádóje ṣékélì, méjèèjì gẹ́gẹ́ bí iye owó ibi mímọ́, àwo kọ̀ọ̀kan sì kún fún ìyẹ̀fun kíkúná dáradára tí a fi òróró pò gẹ́gẹ́ bí ẹbọ ohun jíjẹ́;

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 7

Wo Nọ́ḿbà 7:37 ni o tọ