Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 5:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nípa mímú kí ọkùnrin mìíràn bá a lò pọ̀ tí ó sì fi èyí pamọ́ fún ọkọ rẹ̀, tí a kò si gbá a mú nínú ìwà àìmọ́ rẹ̀ (nítorí pé kò sí ẹlẹ́rìí àti pé wọn kò ká a mọ́ nígbà tí ó ń dẹ́ṣẹ̀ náà).

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 5

Wo Nọ́ḿbà 5:13 ni o tọ