Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 4:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Kí wọn kí ó fi aṣọ aláwọ̀ búlù bọ ọ̀pá fìtílà àti fìtílà rẹ̀, àti àwo ìkó ẹ̀mu sí, àti gbogbo ohun èlò òróró rẹ̀, èyí tí wọ́n fi ń ṣe iṣẹ́ rẹ̀.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 4

Wo Nọ́ḿbà 4:9 ni o tọ