Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 4:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lórí tabilì ìfihàn ni kí wọn ó na aṣọ aláró kan sí, wọn ó sì kó àwọn àwo, páànù, àwokòtò àti ìgò fún ọrẹ ohun mímu; àkàrà tó sì máa ń wà níbẹ̀ ní gbogbo ìgbà náà gbọ́dọ̀ wà níbẹ̀.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 4

Wo Nọ́ḿbà 4:7 ni o tọ