Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 4:49 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n yan iṣẹ́ àti àwọn ohun tí ẹni kọ̀ọ̀kan yóò máa gbé fún un gẹ́gẹ́ bí Olúwa ti pàṣẹ láti ẹnu Mósè.Bẹ́ẹ̀ ni wọ́n ṣe kà wọ́n gẹ́gẹ́ bí Olúwa ti pàṣẹ fún Mósè.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 4

Wo Nọ́ḿbà 4:49 ni o tọ