Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 4:47 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbogbo ọkùnrin láti ọmọ ọgbọ̀n ọdún títí dé àádọ́ta, àwọn tó ń ṣiṣẹ́ ìsìn tó sì ń ru àwọn erù inú Àgọ́ Ìpadé.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 4

Wo Nọ́ḿbà 4:47 ni o tọ