Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 4:45 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èyí ni àpapọ̀ iye àwọn ọmọ Mérárì. Mósè àti Árónì kà wọ́n gẹ́gẹ́ bí àṣẹ Olúwa láti ẹnu Mósè.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 4

Wo Nọ́ḿbà 4:45 ni o tọ