Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 35:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìlú tí ẹ fún àwọn ọmọ Léfì láti ara ilẹ̀ tí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì jogún, olúkúlùkù kí ó fi nínú ìlú rẹ̀ fún àwọn ọmọ Léfì gẹ́gẹ́ bí ilẹ̀ ìní rẹ̀ tí ó ní. Gba púpọ̀ lọ́wọ́ ẹ̀yà tí ó ní púpọ̀ àti díẹ̀ lọ́wọ́ ẹ̀yà tí ó ní díẹ̀.”

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 35

Wo Nọ́ḿbà 35:8 ni o tọ