Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 34:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mósè pa á láṣẹ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé: “Yan ilẹ̀ yìí pẹ̀lú kèké gẹ́gẹ́ bí ìní ogún: Olúwa ti paláṣẹ láti fi fún ẹ̀yà mẹ́san, àti ààbọ̀.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 34

Wo Nọ́ḿbà 34:13 ni o tọ