Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 29:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“ ‘Ní ijọ́ kẹẹdógún oṣù kéje, kí ẹ̀yin kí ó ní àpèjọ mímọ́, ẹ̀yin kò sì gbọdọ̀ ṣe iṣẹ́ kankan. Kí ẹ̀yin kí ó ṣi ṣe àjọyọ̀ fún Olúwa fún ọjọ́ méje.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 29

Wo Nọ́ḿbà 29:12 ni o tọ