Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 29:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Pẹ̀lú akọ ewúrẹ́ kan fún ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀, pẹ̀lú ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ fún ètùtù àti ẹbọ sísun gbogbo ìgbà àti ẹbọ jíjẹ rẹ̀ àti ẹbọ mímu wọn.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 29

Wo Nọ́ḿbà 29:11 ni o tọ