Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 28:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sọ fún wọn, ‘Èyí ní ọrẹ ẹbọ tí a fi iná sun tí ẹ gbọdọ̀ mú wá fún Olúwa: akọ ọ̀dọ́ àgùntàn méjì ọlọ́dún kan aláìlábàwọ́n gẹ́gẹ́ bí ẹbọ ọrẹ sísun ní ojojúmọ́.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 28

Wo Nọ́ḿbà 28:3 ni o tọ