Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 28:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ní òfin yìí kí o sì wí fún wọn pé: ‘Ẹ rí i wí pé ẹ gbé e wá sí iwájú mi ní àkókò tí a ti yàn, oúnjẹ ọrẹ ẹbọ mi tí a fi iná ṣe sí mi, gẹ́gẹ́ bí òórùn dídùn sí mi.’

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 28

Wo Nọ́ḿbà 28:2 ni o tọ