Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 27:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Baba wa kú sí ihà. Kò sí lára àwọn ẹgbẹ́ Kórà tí wọ́n kó ara wọn pọ̀ lòdì sí Olúwa, Ṣùgbọ́n ó kú nítórí ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀ kò sì fi ọmọkùnrin sílẹ̀.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 27

Wo Nọ́ḿbà 27:3 ni o tọ