Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 27:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí ó dúró níwájú Élíásárì àlùfáà, tí yóò gba ìpinnu fún láti béèrè Úrímù níwájú Olúwa. Gẹ́gẹ́ bí òfin yìí ni òun pẹ̀lú gbogbo ìjọ ènìyàn Ísírẹ́lì yóò jáde lọ, pẹ̀lú òfin rẹ̀ sì ni wọn ó wọlé.”

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 27

Wo Nọ́ḿbà 27:21 ni o tọ