Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 27:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ní Olúwa sọ fún Mósè pé, “Mú Jóṣúà ọmọ Núnì, ọkùnrin nínú ẹni tí èmi wà, kí o sì gbé ọwọ́ rẹ lé e.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 27

Wo Nọ́ḿbà 27:18 ni o tọ