Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 27:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

nítórí nígbà tí ìlú ṣọ̀tẹ̀ níbi omi ní Aginjù Ṣínì, tí gbogbo yín se àìgbọ́ràn sí mi láti yà mí sí mímọ́ níwájú wọn.” (Èyí ni omi Méríbà ní Kádésì ní ihà Sínì.)

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 27

Wo Nọ́ḿbà 27:14 ni o tọ