Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 27:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Tí baba rẹ̀ kò bá ní arákùnrin, fún ará ilé rẹ̀ tí ó bá súnmọ́ jù ní ìdílé rẹ̀ ní ogún ìní rẹ̀, kí ó lè jogún rẹ̀. Èyí gbọdọ̀ jẹ́ ìlànà ìdájọ́ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì gẹ́gẹ́ bí Olúwa ti paláṣẹ fún Mósè.’ ”

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 27

Wo Nọ́ḿbà 27:11 ni o tọ