Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 26:58 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ̀nyí ni ìdílé àwọn ọmọ Léfì;ìdílé àwọn ọmọ Líbínì,ìdílé àwọn ọmọ Hébírónì,ìdílé àwọn ọmọ Málì,ìdílé àwọn ọmọ Múṣì,ìdílé àwọn ọmọ Kórà.(Kóhátì ni baba Ámírámù,

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 26

Wo Nọ́ḿbà 26:58 ni o tọ