Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 26:54 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Fún àwọn ọ̀pọ̀ ni kí ìwọ ó fún ní ogún ìlú púpọ̀ àti fún àwọn tí ó kéré ni kí ìwọ ó fi kékeré fún, ẹnìkọ̀ọ̀kan gbọdọ̀ gba ogún ìbí tirẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ènìyàn tí a kọ.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 26

Wo Nọ́ḿbà 26:54 ni o tọ