Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 22:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

rán oníṣẹ́ pé Bálámù ọmọ Béórì, tí ó wà ní Pétórì, ní ẹ̀bá odò ti ilẹ̀ àwọn ènìyàn rẹ. Bálákì sọ pé:“Àwọn ènìyàn kan jáde wá láti Éjíbítì; wọ́n bo gbogbo ilẹ̀ ayé wọ́n sì pa ibùdó súnmọ́ ọ̀dọ̀ mi.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 22

Wo Nọ́ḿbà 22:5 ni o tọ