Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 22:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Móábù sọ fún àwọn àgbààgbà Mídíánì pé, “Nísinsìnyìí ni àwọn wọ̀nyí yóò lá gbogbo ohun tí ó yí wa ká, bí màlúù ṣe ń jẹ koríko tí ó wà nínú oko.” Bẹ́ẹ̀ ni Bálákì ọmọ Ṣípórì, tí ó jẹ́ ọba Móábù nígbà náà,

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 22

Wo Nọ́ḿbà 22:4 ni o tọ