Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 21:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Jẹ́ kí a kọjá ní orílẹ̀ èdè rẹ. A kò ní kọjá sí inú oko pápá tàbí ọgbà tàbí mu omi láti inú kànga. A máa gba òpópónà náà ti ọba títí tí a ó fi la ilẹ̀ rẹ kọjá.”

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 21

Wo Nọ́ḿbà 21:22 ni o tọ