Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 17:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì se ní ọjọ́ kéjì Mósè wọ inú àgọ́ ẹ̀rí lọ, ó sì rí ọ̀pá Árónì, tí ó dúró fún ẹ̀yà Léfì, kì í ṣe wí pé ó hù nìkan Ṣùgbọ́n ó ruwé, ó yọ ìtànná, ó sì so èso jíjẹ.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 17

Wo Nọ́ḿbà 17:8 ni o tọ