Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 17:11-13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

11. Mósè sì ṣe gẹ́gẹ́ bí Olúwa ti pa a láṣẹ fún un.

12. Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sọ fún Mósè pé, “Àwa yóò kú! A ti sọnù, gbogbo wa ti sọnù!

13. Ẹnikẹ́ni tí ó bá súnmọ́ tabánákù Olúwa yóò kú. Ṣé gbogbo wa ni yóò kú?”

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 17