Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 17:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa sọ fún Mósè pé, “Mú ọ̀pá Árónì padà wá ṣíwájú Ẹ̀rí, láti fi pamọ́ gẹ́gẹ́ bí àmìn fún àwọn ọlọ̀tẹ̀. Èyí ó sì mú òpin bá kíkùn sínú wọn sí mi, kí wọn kí ó má baà kú.”

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 17

Wo Nọ́ḿbà 17:10 ni o tọ