Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 15:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹni náà yóò mú ọ̀dọ́ akọ màlúù náà wá pẹ̀lú ọrẹ ohun jíjẹ, ìdá sí mẹ́ta nínú mẹ́wàá òṣùwọ̀n ìyẹ̀fun ìyẹ̀fun kíkúná tí a fi ìdajì òṣùwọ̀n òróro pò.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 15

Wo Nọ́ḿbà 15:9 ni o tọ