Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 15:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí ó tún mú ìdajì òsùwọ̀n wáìnì wá fún ọrẹ ohun mímu. Yóò jẹ́ ọrẹ àfinásun, àní òórùn dídùn sí Olúwa.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 15

Wo Nọ́ḿbà 15:10 ni o tọ