Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 14:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n sì sọ fún gbogbo ìjọ ènìyàn Ísírẹ́lì pé, “Ìlẹ̀ tí a là kọjá láti yẹ̀ wò náà jẹ́ ilẹ̀ tí ó dára lọ́pọ̀lọpọ̀.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 14

Wo Nọ́ḿbà 14:7 ni o tọ