Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 14:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kò sí ọ̀kan nínú àwọn ènìyàn tó rí òg mi àti wọn iṣẹ́ àmì ìyanu tí mo ṣe ní ilẹ̀ Éjíbítì àti nínú ihà ṣùgbọ́n tí wọ́n ṣe àìgbọ́ràn sí mi, tí wọn sì dán mi wò ní ìgbà mẹ́wàá yìí,

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 14

Wo Nọ́ḿbà 14:22 ni o tọ