Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 14:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbogbo ọmọ Ísírẹ́lì sì kùn sí Mósè àti Árónì, gbogbo ìjọ ènìyàn Ísírẹ́lì sì wí fún wọn pé; “Àwa ì bá kúkú ti kú ní ilẹ̀ Éjíbítì. Tàbí kí a kúkú kú sínú ihà yìí.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 14

Wo Nọ́ḿbà 14:2 ni o tọ