Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 14:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

‘Olúwa lọ́ra láti bínú, ó sì pọ̀ ní ìfẹ́ tó dúró sinsin, tí ń dárí ẹ̀ṣẹ̀ àti ìrékọjá jìn. Bẹ́ẹ̀ ni kì í jẹ́ kí ẹlẹ́bi lọ láìjìyà; tó ń fi ìyà ẹ̀ṣẹ̀ baba jẹ ọmọ títí dé ìran kẹta àti ìran kẹrin.’

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 14

Wo Nọ́ḿbà 14:18 ni o tọ