Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 14:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n gbogbo ìjọ ènìyàn sì ń sọ pé àwọn yóò sọ wọ́n lókúta pa. Nígbà náà ni ògo Olúwa fara hàn ní Àgọ́ Ìpàdé níwájú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 14

Wo Nọ́ḿbà 14:10 ni o tọ