Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 1:53 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ọmọ Léfì yóò jẹ́ alábojútó àti olùtọ́jú Àgọ́ Ẹ̀rí náà, kí ìbínú má ba à sí lára ìjọ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì; kí àwọn ọmọ Léfì sì máa ṣe ìtọ́jú Àgọ́ Ẹ̀rí náà.”

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 1

Wo Nọ́ḿbà 1:53 ni o tọ