Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 1:42 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Láti ìran Náfítalì:Gbogbo ọmọkùnrin tí ọjọ́ orí wọn jẹ́ ogún ọdún ó lé, tí wọ́n lè lọ sójú ogun ni wọ́n to orúkọ wọn lẹ́yọ kọ̀ọ̀kan gẹ́gẹ́ bí àkọsílẹ̀ ẹbí àti ìdílé wọn.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 1

Wo Nọ́ḿbà 1:42 ni o tọ