Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 1:13-17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

13. Láti ọ̀dọ̀ Áṣérì, Págíélì ọmọ Ókíránì;

14. Láti ọ̀dọ̀ Gáádì, Élíásàfu ọmọ Déúélì;

15. Láti ọ̀dọ̀ Náfítalì, Áhírà ọmọ Énánì.”

16. Àwọn wọ̀nyìí ni wọ́n yàn nínú àwùjọ ènìyàn, olórí àwọn ẹ̀yà baba wọn. Àwọn ni olórí àwọn ẹbí Ísírẹ́lì.

17. Mósè àti Árónì mú àwọn ènìyàn tí a dárúkọ wọ̀nyí

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 1