Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 1:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa bá Mósè sọ̀rọ̀ ní ihà Ṣínáì nínú àgọ́ àjọ ní ọjọ́ kìn-ín-ní oṣù kejì ní ọdún kejì tí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì jáde kúrò ní ilẹ̀ Éjíbítì, ó wí pé:

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 1

Wo Nọ́ḿbà 1:1 ni o tọ