Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemáyà 9:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Nítorí àánú ńláà rẹ, ìwọ kò kọ̀ wọ́n sílẹ̀ ní ihà. Ní ọ̀sán ọ̀pọ̀ ìkùùkuu kò kúrò ní ọ̀dọ̀ wọn láti ṣe amọ̀nà an wọn, tàbí ọ̀pọ̀ iná láti tàn sí wọn ní òru ní ọ̀nà tí wọn yóò rìn.

Ka pipe ipin Nehemáyà 9

Wo Nehemáyà 9:19 ni o tọ