Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemáyà 9:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kódà nígbà tí wọ́n yá ère dídá (ère ọmọ màlúù) fún ara wọn, tí wọ́n sì wí pé, Èyí ni Ọlọ́run rẹ tí ó mú ọ gòkè láti Éjíbítì wá; tàbí nígbà tí wọ́n sọ ọ̀rọ̀-òdì tí ó burú jàì.

Ka pipe ipin Nehemáyà 9

Wo Nehemáyà 9:18 ni o tọ