Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemáyà 7:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni Ọlọ́run mi fi sí mi ní ọkàn láti kó àwọn ọlọ́lá, àwọn ìjòyè, àti àwọn ènìyàn jọ fún ìforúkọsílẹ̀ ní ìdílé ìdílé. Mo rí ìwé àkọsílẹ̀ ìtàn ìran àwọn tí ó kọ́ gòkè padà wá láti ìgbèkùn. Èyí ni ohun tí mo rí tí a kọ sínú ìwé náà:

Ka pipe ipin Nehemáyà 7

Wo Nehemáyà 7:5 ni o tọ