Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemáyà 6:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n mo wí pé, “Ǹjẹ́ ó yẹ kí irú ènìyàn bí èmi sá lọ? Tàbí kí ènìyàn bí èmi sá lọ sínú tẹ́ḿpìlì láti gba ẹ̀mí ara rẹ̀ là? Èmi kò ní lọ!”

Ka pipe ipin Nehemáyà 6

Wo Nehemáyà 6:11 ni o tọ