Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemáyà 5:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo sì wí fún wọn pé: “Níbi tí àwa ní agbára mọ, àwa ti ra àwọn Júù arákùnrin wa tí a ti tà fún àwọn tí kì í ṣe Júù padà. Nísinsìn yìí ẹ̀yìn ń ta àwọn arákùnrin yín, tí àwa sì tún ní láti rà wọ́n padà!” Wọ́n dákẹ́, nítorí wọn kò rí ohun kóhun sọ.

Ka pipe ipin Nehemáyà 5

Wo Nehemáyà 5:8 ni o tọ