Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemáyà 5:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo rò wọ́n wò ní ọkàn mi mo sì fi ẹ̀ṣùn kan ọlọ́lá àti àwọn ìjòyè. Mo sọ fún wọn pé, ẹ̀yin ń gba owó èlé lọ́wọ́ àwọn ará ìlúu yín! Nítorí náà mo pe àpèjọ ńlá láti bá wọn wí.

Ka pipe ipin Nehemáyà 5

Wo Nehemáyà 5:7 ni o tọ